Awon agba maa hun so wipe «ko dajo “bi ose rewa si”,leyin naa dajo ‘bi ose gbon si’» Ni igba akoko ti o ba koko rii iko agbabolu ohun ti oma je ko nife won nii aso iwogbabolu won. Eyi loofa ti awon eniyan maa n sowipe ko rorun lati ya aworan aso iwo gbabolu.Wahala maa n wa nigba ti iko agbabolu bani lati maase aso titun ni emeji abi emeta laarin odun.

Awon ayaworan miiran maa n gba adura pe ti awon ba di agbabolu awon yoo maa woo awon aso yii tii aye. Oju maati eniyan nigba ti oba wo aso bolu ti oni ewa ti owa nmu aja rin tabi ti otun moto se ninu iru aso yii.

Awon aso iwogbabolu ti korewa ninu Itan niyii

Ipo keje(7th)

Barcelona

Odun::1995

Barcelona je okan laarin awon iko agbabolu ti oni ewa julo ni ipele agbaye ti ko si ribe tele. Igbiyanju lati lo orisirisi oda ati lilo ila leje idi ti awon ololufe se maa hun yin aso Real Madrid.

Ipo kefa(6th)

Liverpool

Odun::1995

Rara aso eleyi kiise fun oko olorin Band Kiss, aso Liverpool nii.Nipa aso yii oruko ti oye ki Liverpool maje ni Thunder FC.

Ipo Karun(5th)

Bochum

Odun::1997

Aso yii pin si ona meji akoko se tan Lati gbabolu ti ikeji si n polongbo ibalopo okunrin si okunrin.

Ipo Kerin(4th)

Dundee

Odun::1953

Ti aba wo aso yi dada osese lati ma wo bolu awon aje funfun ju bolu laasan loo.

Ni akoko naa okunrin ma nwa ni ori igbale ti bola si n fo ninu afefe pelu iye.

Ipo keta(3rd)

Athletico Bilbao

Odun::2004

Mo lero pe mo mon idi ohungbogbo.Aso iwo gbabolu yii funfun bi efun sugbon ni ojo to awon agbabolu lo si KFC ti ketchup baada si aso won.

Ipo Keji(2nd)

Reggina

Odun::2012

Awon eleyi gbiyanju gidigan.Won ko nilo lati ma fosoke fosile ki won to ni ige(6 pack). Ohun kan to eniyan ko nife wo nii soko aso yii.

Ipo Kenin(1st)

Colorado Caribous

Odun::1978

Emi fe iru aso iwo gbabolu yii nii champions league sugbon won gbodo fii awon agbo won sita.

This article is a translation of an article posted by

@Ann

Here is the link to the original post.

https://scorum.com/en-us/football/@ann/7-ugliest-kits-ever

This post has been translated for @scorumbounty.